top of page

Forum Posts

Mojisola Alawode
Mar 26, 2023
In General Discussion
Below is the text and audio file for shadowing for march 26th, 2023. Láti ibí dé ibẹ̀yẹn ni a ti rà. Láti ibi tí ilà wà la ti máa là á. A ti ra gbogbo ibí. A dẹ ti fún àwọn ní gbogbo ibẹ̀yẹn.
0
0
12
Mojisola Alawode
Mar 18, 2023
0
0
4
Mojisola Alawode
Dec 21, 2022
0
0
11
Mojisola Alawode
Oct 31, 2022
In General Discussion
0
0
7
Mojisola Alawode
Oct 10, 2022
In General Discussion
Role Plays

 content media
0
0
25
Mojisola Alawode
Oct 05, 2022
In General Discussion
I BOUGHT NEW PAIRS OF SHOES YESTERDAY. MY FRIENDS LOVED THEM. THEY ASKED ME TO LEND THEM THE SHOES SO THEY COULD WEAR THEM TO THE PARTY TOMORROW. I ASKED THEM TO GO BUY THEIRS. SO, THEY GOT THEIRS BEFORE I GOT TO THE OFFICE TODAY. I WAS SO HAPPY THAT I ASKED ONE OF THEM “ LET’S WEAR OUR NEW SHOES TO OUR BOSS’ BIRTHDAY PARTY SO THAT EVERYONE CAN SEE THEM”. Mo ra àwọn bàtà tuntun lánàá. Àwọn ọ̀rẹ́ mi fẹ́ràn wọn. Wọ́n ní ki n yá àwọn, kí wọ́n ba lè wọ̀ ọ́ lo sí ̀aríyá ọ̀la. Mo ní kí wọ́n lọ ra tiwọn. Wọ́n ra ti wọn kí n tó dé ibi iṣẹ́ leni. Inú mí dùn dé ibi pé mo bère lọ́wọ́ ìkan nínu wón pé “ ẹ jẹ́ kí a wọ àwọn bàtà tuntun wa lọ sí àríyá ọ̀gà kí gbogbo èyàn ba ri wọn.
0
2
14
Mojisola Alawode
Sep 28, 2022
In General Discussion
Hello everyone, here's the link to the interview we would review on Saturday, October first, 2022.
0
6
17
Mojisola Alawode
Sep 25, 2022
In General Discussion
Hello every one, here's what to practice ahead of tomorrow's role plays
0
0
10
Mojisola Alawode
Sep 11, 2022
In General Discussion
Hi everyone, I thought it would be nice for us to review one movie weekly. This, I believe will give focus and speed to the Yoruba learning journey. If you agree with this, I suggest we all see the movie: Mr. Perfect. We would pick our role plays, movie Thursday, Vocabulary, and shadowing exercises from the movie. You can post words or expressions you find challenging in the Question and answer category of this Community Forum. Here is the link to the movie: https://youtu.be/e24V-hYUETg.
0
0
16
Mojisola Alawode
Sep 11, 2022
In General Discussion
Hello every one, here's the audio file and the text for today's shadowing event. Ẹ̀ẹ̀mejì ni mo máa ń jẹun lójúmọ́, nítorípé mi ò fẹ̣́ sanra. Mo fẹ́ kí àwọ̀ mí máa dán, nítorí ẹ̀ ni mo ṣe máa ń jẹ èso dáadáa.
0
1
11
Mojisola Alawode
Aug 28, 2022
In General Discussion
Hello every one, here's an audio file from today's shadowing event: Áàh! ó rè mi ̀gan. Mo ṣì ń ronú àwọn ǹkan tí mo máa ṣé ní ọ̀la, bíi aṣọ fífọ̀, ibi tí ó yẹ kí n jáde lo, àti àti-dáná oun tí mo máa jẹ. Díẹ̀díẹ̀ náà ni máa máa ṣé.
0
1
9
Mojisola Alawode
Aug 11, 2022
In General Discussion
Here's the movie clip transcript;
0
0
16
Mojisola Alawode
Aug 11, 2022
In General Discussion
Hello, please watch this movie clip and study the transcript for role play on Monday, August 15th 2022
MOVIE THURSDAY AND ROLE PLAYS MONDAY content media
0
0
14
Mojisola Alawode
Aug 03, 2022
In General Discussion
Today, we looked at words in Yoruba that mean more than one thing. Please read below examples of such words:
1
1
17
Mojisola Alawode
Jul 31, 2022
In General Discussion
Ẹni ọdún márùndínlógbọ̀n ni Tóbi Amúsàn. Ó jẹ́ eléré ìje. O gba àmì ẹ̀yẹ góòlù nínu ìdíje World Athletics Championship ti odun 2022. Ẹ̀ẹ̀mejì ni ó ṣe ǹkan tí ẹnìkankan ò ṣe rí nínu eré sísá àwọn obìnrin ní àgbáyé ní ọjọ́ kan. Tobi Amusan is 25 years old. She is an athlete. She got a gold medal at the World Athletletics championship of 2022. She broke two world records in one day. Ó gba wúrà ní ere ije ni àkókò tí ó kúrú jù ní ìdíje Championship lagbaye. Ó sá eré ọgọ́run mítà ni Ìṣẹ́jú méjìlá àti ìṣéjú àáyá méjìlá, ó dẹ̀ gba àmì ẹ̀yẹ wúrà nínu ìdíje náà. She won gold and broke world record in the shortest time recorded in World Athletics Championship. She ran hundred metres in 12:12 seconds and got a gold medal in the competition. Tóbi gbé ògo orílẹ̀ èdè Nigeria ga. Wọ́n kọ orin orílẹ̀ èdè Nigeria fún ìgbà àkọ́kọ́ nínu ìdíje náà nítorí ǹkan tí ó ṣe. Tobi lifted the glory of Nigeria. Nigerian anthem was sung for the first time in the competition because of what she did. Ó ní òún ti rí oríṣiríṣi ìpèníjà nítorí eré sísá. Ó ní àwọn òbí òun ò gba gbẹ̀rẹ́ rárá. Bàbá ẹ̀ fẹ́ kí ó ka ìwé nìkan ṣùgbọ́n màmá ẹ̀ rò pé ó yẹ kí àwọn fún un láyè láti ṣe ǹkan tó wù ú. Bàbá ẹ̀ ò nífẹ̀ sí eré sísá ṣùgbọ́n màmá Tóbi tìí lẹ́yìn. Koda, màmá ẹ̀ máa ń parọ́ fún bàbá ẹ̀ nípa ibi tí ó lọ tí ó bá ti lọ gbáradì fún eré sísá tàbí tí ó bá lọ fún ìdíje. She said she has seen different challenges in Athletics. She said her parents are “no nonsense” people. Her father wanted her to get education alone but her mother thought they should give her a chance to do what she loved to do. Her father did not like Athletics but her mother supported her.Infact, her mother used to lie to her father about where she went for athletics practice or for competitions. Nígbà tí bàbá ẹ̀ mọ òótọ́, ó sun aṣọ eré sísá ẹ . Ó wá kìlọ̀ fún màmá ẹ̀ pé kí ìyẹ́n jẹ́ ìgbà ìkẹyìn tí òun máa rí Tobi ní ìdi eré ìdárayá. Bàba Tóbi ò ní ìgbàgbọ́ nínu eré sísá ṣùgbọ́n Tóbi ní ìgbàgbọ́ nínú ara ẹ̀. Ìgbàgbọ́ yìí ló jẹ́ kí ó borí nínu ìdíje náà. When her father knew the truth, he burnt her sports kit. He then warned her mother that that should be the last time that he would see Tobi around sports. Tobi’s father did not believe in Athletics but Tobi believed in herself. It was this belief that made her win in the competition. Àrẹ orílẹ̀ èdè Nigeria àti àwọn èyàn ńláńlá ní Nigeria ti kí Tóbi kú oríire fún àṣeyọrí yìí. Ó mú ìwúrí bá orin orílẹ̀ èdè Nigeria tí wọ́n kọ nígbà tí ó gba àmì ẹ̀yẹ góòlù náà. Iṣẹ́ takuntakun tó ṣe mú ayọ̀ àti ìdùnú bá gbogbo àwọn ọmọ Nigeria. Ó ṣiṣẹ́ takuntakun, ó dè rí ère ẹ̀. The President of Nigeria and some “big” people in Nigeria have congratulated Tobi for this success. She brought pride which was sung when she received the gold medal. Her hard work brought joy and happiness to all Nigerians. She worked hard, and she saw the reward.
0
5
23
Mojisola Alawode

Mojisola Alawode

Admin
More actions
bottom of page